Contact Akahi Rep - 08038644328
Education

Practice FREE JUPEB YORUBA – ART –J129 Past Questions Essay and Objectives

Practice FREE JUPEB YORUBA – ART –J129 Past Questions Essay and Objectives

Advertisements

JOINT UNIVERSITIES PRELIMINARY EXAMINATIONS BOARD (JUPEB)

2015 EXAMINATIONS YORUBA – ART –J129

Register Your Business or Company Name With CAC

MULTIPLE CHOICE QUESTIONS

1.    Ònìsà jẹ ọrọ tí a yá lò láti inú èdè wo?

A.   Haúsá

B.   Ìgbò

C.   Faransé

D.   Lárúbáwá

2.    Àwọn àmì-ohùn wo ni a fi pe ALUFAA

A.   Ìsàlẹ Ìsàlẹ òkè ìsàlẹ B.   Òkè òkè ìsàlẹ ìsàlẹ C.   Ààrin ààrin òkè òkè

D.   Òkè Ìsàlẹ Àràrin oke

3.    Àwon ìró fáwẹlì àyanudíẹpè ni

A.   e ẹ ọ an

B.   e o ẹ ọ

C.   ẹ ọ ẹn ọn

D.   i u e o

4.    Bátànì sílébù inúAṢENIBÁNIDÁRÒ ni

A.   FK-KF-KF-N-KF-KF

B.   F-KF-KF-KF-KF-KF-KF C.   KF-N-KF-KF-N-KF-KF D.   F-KF-KF-KF-KF-KF

5.    Èwo ni àpẹẹrẹ àyálò ọrọ láti inú èdè Lárùbáwá?

A.   Ṣinmí B.   Káàdì C.   Àlùfáà D    Dafidi

Pages: 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11

Leave a Reply

Your email address will not be published.